languageIcon
search
search

Àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí a máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ àti alaalẹ́

SleepAdhkar
Àwọn ìrántí Ọlọ́hun tó wà fún oorun sísùn

Bíbẹ̀rẹ̀ ọjọ́ titun pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti odi-ìṣọ́ tí yóò máa ṣọ́ ẹ ní àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́, pẹ̀lú àwọn ìrántí Ọlọ́hun péréte tí yóò jẹ́ okùnfà ìṣọ́ fún ẹ ní ọ̀sán ọjọ́ tí o wà yìí, nítorí náà má ṣe ṣe ahun sí ẹ̀mí ara rẹ̀, pẹ̀lú pípa àwọn ìrántí Ọlọ́hun, tí a máa ń ṣe ní àárọ̀ tì, nítorí pé ó jẹ́ ohun tí ó máa ń ṣọ́ Mùsùlùmí, ó sì máa ń fún un ní ìfàyàbalẹ̀, ó ń bọ̀ wáá rí àwọn ìrántí Ọlọ́hun tó wà fún oorun sísùn pé pérépéré.

Ṣe àfihàn
AfteroonAdhkar
Àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí a máa ń ṣe ní ìrọ̀lẹ́

Bíbẹ̀rẹ̀ ọjọ́ titun pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti odi-ìṣọ́ tí yóò máa ṣọ́ ẹ ní àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́, pẹ̀lú àwọn ìrántí Ọlọ́hun péréte tí yóò jẹ́ okùnfà ìṣọ́ fún ẹ ní òru ọjọ́ tí o wà yìí, nítorí náà má ṣe ṣe ahun sí ẹ̀mí ara rẹ̀, pẹ̀lú pípa àwọn ìrántí Ọlọ́hun, tí a máa ń ṣe ní ìrọ̀lẹ́ tì, nítorí pé ó jẹ́ ohun tí ó máa ń ṣọ́ Mùsùlùmí, ó sì máa ń fún un ní ìfàyàbalẹ̀, ó ń bọ̀ wáá rí àwọn ìrántí Ọlọ́hun náà

Ṣe àfihàn
morningAthkar
Àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí a máa ń ṣe ní àárọ̀

Bíbẹ̀rẹ̀ ọjọ́ titun pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti odi-ìṣọ́ tí yóò máa ṣọ́ ẹ ní àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́, pẹ̀lú àwọn ìrántí Ọlọ́hun péréte tí yóò jẹ́ okùnfà ìṣọ́ fún ẹ ní ọ̀sán ọjọ́ tí o wà yìí, nítorí náà má ṣe ṣe ahun sí ẹ̀mí ara rẹ̀, pẹ̀lú pípa àwọn ìrántí Ọlọ́hun, tí a máa ń ṣe ní àárọ̀ tì, nítorí pé ó jẹ́ ohun tí ó máa ń ṣọ́ Mùsùlùmí, ó sì máa ń fún un ní ìfàyàbalẹ̀, ó ń bọ̀ wáá rí àwọn ìrántí Ọlọ́hun náà

Ṣe àfihàn
talqeenRight
التلقين

Títẹ́tí sí olùkọ̀ọ́


Ìranlọ́wọ́ tí a ó ṣe fún ọ láti ràn ọ lọ́wọ́ lóríi pípe àwọn Sūrah Al-Qur’ān kékèèké àti àwọn ìrántí Ọlọ́hun tó fi ẹsẹ̀ rinlẹ̀ ní ọ̀nà tó ní àlááfíà

. Ṣíṣe mímáa pààrà nǹkan láti ìgbà dégbà ní ìrọ̀rùn, nítorí àti fi ohun tí a há rinlẹ̀ àti pípe nǹkan ní ọ̀nà tó ní àlááfíà

. A ó mú àwọn fọ́nrán ohún wá fún ọ, pẹ̀lú èyí tó rẹwà jùlọ, tó sì hàn kedere júlọ nínú ohùn àwọn àlùfáà tó ka Al-Qur’ān

Bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkọ́